Saturday, July 25, 2020

Happy 60th. TO.

Ejire ààrá Ìrósun, ọmọ Èédùnjọbi
Wíní wíni lojú orógun, èjì woro ni ojú ìyá ẹ.
Ọkàn mọ fẹ, èejì ló wọlé tọ mi
Omo bẹ bẹ, ó fi ẹsẹ méjèèjì bẹ.
Ó bẹ sì ilé alákìsà sọ wọn di òní gbà aṣọ.
But mi kin bá ọ relé, kii mi kín ń padà sẹ́yìn.
Ń bá bí èjìre ń a jọ, ai bí èjìre dùn mi.
Nítorí wípé eepo mbẹ, ẹwà mbẹ.
Aya mi ò sì já, láti bí beji
Ògotá Ọdún, Ọdún kàn.
Osi Aare lo so be, Aase gun.
My10kobo
Image may contain: 1 person

No comments:

Post a Comment

NEW HOME, CAR OWNERS EMERGE AS COWLSO ENDS THREE DAY WOMEN'S CONFERENCE.

As the 23rd edition of the National Women's Conference organized by the Committee of Wives of Lagos State Officials (COWLSO), ends today...