Aara me riri,
Mo ri ori ologbo la te,
Adetunji do, Adetunji di Kabiyesi l'Ojaba o!!!!
Mo ri ori ologbo la te,
Adetunji do, Adetunji di Kabiyesi l'Ojaba o!!!!
Oba Sansalihu mi oooo
Aduro tini ni igba to soro Adetunji o
Aduro tini lojo to buru o
Aduro tini lojo eeye o
Orin lo mba mi so Alakanmu o
Oba Salihu, Akanmu Adetunji
Aduro tini ni igba to soro Adetunji o
Aduro tini lojo to buru o
Aduro tini lojo eeye o
Orin lo mba mi so Alakanmu o
Oba Salihu, Akanmu Adetunji
Bi iberu, bi isaju
Ni mu omode gun igi ope gbongbona
Oluwa a ms so e, Akanmu o
Eni pe o ku asiwaju e ku,
Eni pe o ku a gbo bi aja ku,
Oro bi ekun ki ba awoko, owo ni labalaba fi kari wogbo
Ni mu omode gun igi ope gbongbona
Oluwa a ms so e, Akanmu o
Eni pe o ku asiwaju e ku,
Eni pe o ku a gbo bi aja ku,
Oro bi ekun ki ba awoko, owo ni labalaba fi kari wogbo
Family meji lo wa, Nile site
To ba lowo , ikan a feran e,
Bi o si ni, won a ma bu e
To ba lowo , ikan a feran e,
Bi o si ni, won a ma bu e
Aje ogunguniso, ko wa ba mi gbele,
Mo fenu pe ifa, ifa a wole towa yika
Bi ojumo ba mo, mo ji mala,
Mo yan ori ayo nitemi.
Mo fenu pe ifa, ifa a wole towa yika
Bi ojumo ba mo, mo ji mala,
Mo yan ori ayo nitemi.
Kabiyesi, Oba Saliu Akanmu Adetunji,
Aje Ogunguniso 1
Ki Ade pe Lori, ki bata pe lese
Ki irukere di abere.
Aje Ogunguniso 1
Ki Ade pe Lori, ki bata pe lese
Ki irukere di abere.
Aakogun Amunigun lo sobe, Aase gun!
My Ten Kobo
No comments:
Post a Comment